-
Ìsíkíẹ́lì 10:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 tí àwọn kérúbù náà bá sì gbéra, àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ náà á gbéra pẹ̀lú wọn; tí wọ́n bá sì na ìyẹ́ apá wọn kí wọ́n lè lọ sókè, àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ náà kì í yí tàbí kí wọ́n kúrò lẹ́gbẹ̀ẹ́ wọn.+
-