Ẹ́kísódù 32:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Mósè wá bẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,*+ ó sọ pé: “Jèhófà, kí ló dé tí wàá fi bínú gidigidi sí àwọn èèyàn rẹ, lẹ́yìn tí o fi agbára ńlá àti ọwọ́ agbára mú wọn kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì?+ Sáàmù 106:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Díẹ̀ ló kù kó sọ pé kí wọ́n pa wọ́n rẹ́,Àmọ́ Mósè àyànfẹ́ rẹ̀ bá wọn bẹ̀bẹ̀*Láti yí ìbínú rẹ̀ tó ń pani run pa dà.+
11 Mósè wá bẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,*+ ó sọ pé: “Jèhófà, kí ló dé tí wàá fi bínú gidigidi sí àwọn èèyàn rẹ, lẹ́yìn tí o fi agbára ńlá àti ọwọ́ agbára mú wọn kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì?+
23 Díẹ̀ ló kù kó sọ pé kí wọ́n pa wọ́n rẹ́,Àmọ́ Mósè àyànfẹ́ rẹ̀ bá wọn bẹ̀bẹ̀*Láti yí ìbínú rẹ̀ tó ń pani run pa dà.+