Ìsíkíẹ́lì 16:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ibi tó gbàfiyèsí jù ní gbogbo ojú ọ̀nà lo kọ́ àwọn ibi gíga rẹ sí, o sì sọ ẹwà rẹ di ohun ìríra bí o ṣe ń bá gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ ṣèṣekúṣe,*+ o sì wá jingíri sínú iṣẹ́ aṣẹ́wó.+
25 Ibi tó gbàfiyèsí jù ní gbogbo ojú ọ̀nà lo kọ́ àwọn ibi gíga rẹ sí, o sì sọ ẹwà rẹ di ohun ìríra bí o ṣe ń bá gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ ṣèṣekúṣe,*+ o sì wá jingíri sínú iṣẹ́ aṣẹ́wó.+