-
Ìsíkíẹ́lì 25:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 torí náà, èmi yóò mú kí ọwọ́ àwọn ará Ìlà Oòrùn tẹ̀ ọ́, wàá sì di ohun ìní wọn. Wọ́n á kọ́ àwọn ibùdó* wọn sínú rẹ, wọ́n á sì pàgọ́ wọn sáàárín rẹ. Wọ́n á jẹ èso rẹ, wọ́n á sì mu wàrà rẹ.
-