Sekaráyà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Tírè kọ́ odi ààbò* fún ara rẹ̀. Ó to fàdákà jọ pelemọ bí iyẹ̀pẹ̀Àti wúrà bí iyẹ̀pẹ̀ ojú ọ̀nà.+