Àìsáyà 14:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kàkà bẹ́ẹ̀, a máa sọ̀ ọ́ kalẹ̀ lọ sínú Isà Òkú,*Sí àwọn ibi tó jìnnà jù nínú kòtò.