-
Ìsíkíẹ́lì 27:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Àwọn oníṣòwò tó wà láwọn orílẹ̀-èdè yóò súfèé torí ohun tó ṣẹlẹ̀ sí ọ.
Ìparun rẹ yóò dé lójijì, yóò sì burú jáì,
O ò sì ní sí mọ́ títí láé.’”’”+
-