ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 23:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Kí ojú tì ọ́, ìwọ Sídónì, ìwọ ibi ààbò òkun,

      Torí òkun ti sọ pé:

      “Mi ò ní ìrora ìrọbí, mi ò sì tíì bímọ,

      Bẹ́ẹ̀ ni mi ò tọ́ àwọn ọ̀dọ́kùnrin tàbí ọ̀dọ́bìnrin* dàgbà.”+

  • Jeremáyà 25:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+

  • Jeremáyà 25:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 gbogbo ọba Tírè, gbogbo ọba Sídónì+ àti àwọn ọba erékùṣù tó wà ní ẹ̀gbẹ́ òkun,

  • Ìsíkíẹ́lì 32:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 “‘Gbogbo àwọn ìjòyè* àríwá wà níbẹ̀, pẹ̀lú gbogbo àwọn ará Sídónì,+ tí wọ́n fi ìtìjú lọ sísàlẹ̀ pẹ̀lú àwọn tí wọ́n pa, láìka bí wọ́n ṣe fi agbára wọn dẹ́rù bani sí. Wọn yóò dùbúlẹ̀ láìdádọ̀dọ́* pẹ̀lú àwọn tí wọ́n fi idà pa, ojú á sì tì wọ́n pẹ̀lú àwọn tó ń lọ sínú kòtò.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́