Ọbadáyà 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí ọjọ́ tí Jèhófà fẹ́ bá gbogbo orílẹ̀-èdè jà ti sún mọ́lé.+ Ohun tí o ṣe ni wọn yóò ṣe sí ọ.+ Ìwà tí o hù sí àwọn èèyàn ni wọn yóò hù sí ọ.
15 Nítorí ọjọ́ tí Jèhófà fẹ́ bá gbogbo orílẹ̀-èdè jà ti sún mọ́lé.+ Ohun tí o ṣe ni wọn yóò ṣe sí ọ.+ Ìwà tí o hù sí àwọn èèyàn ni wọn yóò hù sí ọ.