-
Ìsíkíẹ́lì 29:19, 20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 “Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Èmi yóò fún Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ yóò kó ọrọ̀ rẹ̀ lọ, yóò sì kó ọ̀pọ̀ ẹrù rẹ̀, yóò kó o bọ̀ láti ogun; ìyẹn yóò sì jẹ́ èrè fún àwọn ọmọ ogun rẹ̀.’
20 “‘Torí iṣẹ́ tó ṣe fún mi, èmi yóò fún un ní ilẹ̀ Íjíbítì láti fi ṣe èrè iṣẹ́ àṣekára tó ṣe láti gbógun tì í,’*+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
-