-
Ìsíkíẹ́lì 30:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò mú kí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì pa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ àwọn ará Íjíbítì run.+ 11 Òun àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀, àwọn tó burú jù nínú àwọn orílẹ̀-èdè+ yóò wá láti pa ilẹ̀ náà run. Wọ́n á fa idà wọn yọ láti bá Íjíbítì jà, wọ́n á sì fi òkú àwọn tí wọ́n pa kún ilẹ̀ náà.+
-
-
Hábákúkù 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Wọ́n yára bolẹ̀ káàkiri ayé
Láti gba àwọn ilé tí kì í ṣe tiwọn.+
-