-
Ìsíkíẹ́lì 31:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Mo mú kó rẹwà, kí ewé rẹ̀ sì pọ̀ rẹpẹtẹ,
Gbogbo igi yòókù tó wà ní Édẹ́nì, nínú ọgbà Ọlọ́run tòótọ́ sì ń jowú rẹ̀.’