Ìsíkíẹ́lì 29:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Èmi yóò pa ọ́ tì sínú aṣálẹ̀, ìwọ àti gbogbo ẹja odò Náílì rẹ. Orí pápá gbalasa ni wàá ṣubú sí, wọn ò ní kó ọ jọ, wọn ò sì ní ṣà ọ́ jọ.+ Màá fi ọ́ ṣe oúnjẹ fún àwọn ẹranko orí ilẹ̀ àti àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run.+
5 Èmi yóò pa ọ́ tì sínú aṣálẹ̀, ìwọ àti gbogbo ẹja odò Náílì rẹ. Orí pápá gbalasa ni wàá ṣubú sí, wọn ò ní kó ọ jọ, wọn ò sì ní ṣà ọ́ jọ.+ Màá fi ọ́ ṣe oúnjẹ fún àwọn ẹranko orí ilẹ̀ àti àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run.+