Ìsíkíẹ́lì 29:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Èmi yóò fún Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ yóò kó ọrọ̀ rẹ̀ lọ, yóò sì kó ọ̀pọ̀ ẹrù rẹ̀, yóò kó o bọ̀ láti ogun; ìyẹn yóò sì jẹ́ èrè fún àwọn ọmọ ogun rẹ̀.’
19 “Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Èmi yóò fún Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ yóò kó ọrọ̀ rẹ̀ lọ, yóò sì kó ọ̀pọ̀ ẹrù rẹ̀, yóò kó o bọ̀ láti ogun; ìyẹn yóò sì jẹ́ èrè fún àwọn ọmọ ogun rẹ̀.’