Sáàmù 107:33, 34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ó ń sọ àwọn odò di aṣálẹ̀,Ó sì ń sọ ìṣàn omi di ilẹ̀ tó gbẹ táútáú,+ 34 Ó ń sọ ilẹ̀ eléso di aṣálẹ̀,+Nítorí ìwà burúkú àwọn tó ń gbé orí rẹ̀. Ìsíkíẹ́lì 29:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Èmi yóò mú kí ilẹ̀ Íjíbítì di ahoro ju àwọn ilẹ̀ yòókù lọ, àwọn ìlú rẹ̀ yóò sì ṣófo ju àwọn ìlú yòókù lọ fún ogójì (40) ọdún;+ màá tú àwọn ará Íjíbítì ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè, màá sì fọ́n wọn ká sí àwọn ilẹ̀.”+
33 Ó ń sọ àwọn odò di aṣálẹ̀,Ó sì ń sọ ìṣàn omi di ilẹ̀ tó gbẹ táútáú,+ 34 Ó ń sọ ilẹ̀ eléso di aṣálẹ̀,+Nítorí ìwà burúkú àwọn tó ń gbé orí rẹ̀.
12 Èmi yóò mú kí ilẹ̀ Íjíbítì di ahoro ju àwọn ilẹ̀ yòókù lọ, àwọn ìlú rẹ̀ yóò sì ṣófo ju àwọn ìlú yòókù lọ fún ogójì (40) ọdún;+ màá tú àwọn ará Íjíbítì ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè, màá sì fọ́n wọn ká sí àwọn ilẹ̀.”+