Jẹ́nẹ́sísì 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọmọ Jáfẹ́tì ni Gómérì,+ Mágọ́gù,+ Mádáì, Jáfánì, Túbálì,+ Méṣékì+ àti Tírásì.+ Ìsíkíẹ́lì 38:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ọmọ èèyàn, dojú kọ Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù,+ olórí ìjòyè* Méṣékì àti Túbálì,+ kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí i.+
2 “Ọmọ èèyàn, dojú kọ Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù,+ olórí ìjòyè* Méṣékì àti Túbálì,+ kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí i.+