Àìsáyà 56:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Afọ́jú ni àwọn olùṣọ́ rẹ̀,+ ìkankan nínú wọn ò kíyè sí i.+ Ajá tí kò lè fọhùn ni gbogbo wọn, wọn ò lè gbó.+ Wọ́n ń mí hẹlẹ, wọ́n sì dùbúlẹ̀; wọ́n fẹ́ràn oorun.
10 Afọ́jú ni àwọn olùṣọ́ rẹ̀,+ ìkankan nínú wọn ò kíyè sí i.+ Ajá tí kò lè fọhùn ni gbogbo wọn, wọn ò lè gbó.+ Wọ́n ń mí hẹlẹ, wọ́n sì dùbúlẹ̀; wọ́n fẹ́ràn oorun.