Léfítíkù 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà. Ìsíkíẹ́lì 18:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “‘Àmọ́ tí ẹni burúkú bá yí pa dà kúrò nínú iṣẹ́ ibi tó ti ṣe, tó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ohun tó tọ́ àti ohun tó jẹ́ òdodo, ó máa dá ẹ̀mí* rẹ̀ sí.+
5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà.
27 “‘Àmọ́ tí ẹni burúkú bá yí pa dà kúrò nínú iṣẹ́ ibi tó ti ṣe, tó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ohun tó tọ́ àti ohun tó jẹ́ òdodo, ó máa dá ẹ̀mí* rẹ̀ sí.+