Ìsíkíẹ́lì 18:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “‘Àmọ́ tí ẹni burúkú bá yí pa dà kúrò nínú iṣẹ́ ibi tó ti ṣe, tó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ohun tó tọ́ àti ohun tó jẹ́ òdodo, ó máa dá ẹ̀mí* rẹ̀ sí.+
27 “‘Àmọ́ tí ẹni burúkú bá yí pa dà kúrò nínú iṣẹ́ ibi tó ti ṣe, tó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ohun tó tọ́ àti ohun tó jẹ́ òdodo, ó máa dá ẹ̀mí* rẹ̀ sí.+