Sefanáyà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn olórí tó wà nínú rẹ̀ jẹ́ kìnnìún tó ń ké ramúramù.+ Àwọn onídàájọ́ rẹ̀ jẹ́ ìkookò ní alẹ́;Wọn kì í jẹ egungun kankan kù di òwúrọ̀.
3 Àwọn olórí tó wà nínú rẹ̀ jẹ́ kìnnìún tó ń ké ramúramù.+ Àwọn onídàájọ́ rẹ̀ jẹ́ ìkookò ní alẹ́;Wọn kì í jẹ egungun kankan kù di òwúrọ̀.