ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 2:49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 Bí Dáníẹ́lì sì ṣe béèrè, ọba yan Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò+ láti máa bójú tó ìpínlẹ̀* Bábílónì, àmọ́ Dáníẹ́lì ń ṣiṣẹ́ ní ààfin ọba.

  • Dáníẹ́lì 3:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Àmọ́ àwọn Júù kan wà tí o yàn pé kí wọ́n máa bójú tó ìpínlẹ̀* Bábílónì, ìyẹn Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò.+ Àwọn ọkùnrin yìí ò kà ọ́ sí rárá, ọba. Wọn ò sin àwọn ọlọ́run rẹ, wọ́n sì kọ̀ láti jọ́sìn ère wúrà tí o gbé kalẹ̀.”

  • Dáníẹ́lì 3:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Nebukadinésárì wá kéde pé: “Ẹ yin Ọlọ́run Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò,+ tó rán áńgẹ́lì rẹ̀, tó sì gba àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé e, wọ́n sì kọ̀ láti tẹ̀ lé àṣẹ ọba, wọ́n ṣe tán láti kú* dípò kí wọ́n sin ọlọ́run míì yàtọ̀ sí Ọlọ́run wọn tàbí kí wọ́n jọ́sìn rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́