-
Dáníẹ́lì 2:47, 48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
47 Ọba sọ fún Dáníẹ́lì pé: “Lóòótọ́, Ọlọ́run àwọn ọlọ́run àti Olúwa àwọn ọba ni Ọlọ́run yín, ó sì jẹ́ Ẹni tó ń ṣí àwọn àṣírí payá, torí pé o rí àṣírí yìí ṣí payá.”+ 48 Ọba wá gbé Dáníẹ́lì ga, ó fún un ní ọ̀pọ̀ ẹ̀bùn tó dáa, ó sì fi ṣe alákòóso lórí gbogbo ìpínlẹ̀* Bábílónì+ àti olórí àwọn aṣíwájú gbogbo amòye Bábílónì.
-