-
Dáníẹ́lì 5:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àwọn ìka ọwọ́ èèyàn fara hàn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ̀wé síbi tí wọ́n rẹ́ lára ògiri ààfin ọba níwájú ọ̀pá fìtílà, ọba sì ń rí ẹ̀yìn ọwọ́ náà bó ṣe ń kọ̀wé.
-