-
Dáníẹ́lì 4:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Èmi Nebukadinésárì wà nínú ilé mi, ọkàn mi balẹ̀, nǹkan sì ń lọ dáadáa fún mi ní ààfin mi. 5 Mo lá àlá kan tó dẹ́rù bà mí. Bí mo ṣe dùbúlẹ̀ sórí ibùsùn mi, àwọn àwòrán àti ìran tí mo rí dáyà já mi.+
-