Àìsáyà 30:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ó yá, lọ, kọ ọ́ sára wàláà níṣojú wọn,Kí o sì kọ ọ́ sínú ìwé,+Kó lè wúlò lọ́jọ́ ọ̀la,Láti jẹ́ ẹ̀rí tó máa wà títí láé.+ Hábákúkù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà wá dá mi lóhùn pé: “Kọ ìran náà sílẹ̀, kí o sì kọ ọ́ sára wàláà,+ kó hàn kedere,Kí ẹni tó ń kà á sókè lè rí i kà dáadáa.*+ Ìfihàn 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 ó sọ pé: “Kọ ohun tí o rí sínú àkájọ ìwé, kí o sì fi ránṣẹ́ sí àwọn ìjọ méje tó wà ní: Éfésù,+ Símínà,+ Págámù,+ Tíátírà,+ Sádísì,+ Filadéfíà+ àti Laodíkíà.”+
8 “Ó yá, lọ, kọ ọ́ sára wàláà níṣojú wọn,Kí o sì kọ ọ́ sínú ìwé,+Kó lè wúlò lọ́jọ́ ọ̀la,Láti jẹ́ ẹ̀rí tó máa wà títí láé.+
2 Jèhófà wá dá mi lóhùn pé: “Kọ ìran náà sílẹ̀, kí o sì kọ ọ́ sára wàláà,+ kó hàn kedere,Kí ẹni tó ń kà á sókè lè rí i kà dáadáa.*+
11 ó sọ pé: “Kọ ohun tí o rí sínú àkájọ ìwé, kí o sì fi ránṣẹ́ sí àwọn ìjọ méje tó wà ní: Éfésù,+ Símínà,+ Págámù,+ Tíátírà,+ Sádísì,+ Filadéfíà+ àti Laodíkíà.”+