Sáàmù 104:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 104 Jẹ́ kí n* yin Jèhófà.+ Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run mi, o tóbi gan-an.+ O fi ògo* àti ọlá ńlá wọ ara rẹ láṣọ.+ 2 O fi ìmọ́lẹ̀+ bora bí aṣọ;O na ọ̀run bí aṣọ àgọ́.+
104 Jẹ́ kí n* yin Jèhófà.+ Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run mi, o tóbi gan-an.+ O fi ògo* àti ọlá ńlá wọ ara rẹ láṣọ.+ 2 O fi ìmọ́lẹ̀+ bora bí aṣọ;O na ọ̀run bí aṣọ àgọ́.+