Sáàmù 50:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọlọ́run wa yóò wá, kò sì ní dákẹ́.+ Iná tó ń jó nǹkan run wà níwájú rẹ̀,+Ìjì tó lágbára sì ń jà ní gbogbo àyíká rẹ̀.+ Sáàmù 97:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Iná ń lọ níwájú rẹ̀,+Ó sì ń jó àwọn ọ̀tá rẹ̀ run yí ká.+
3 Ọlọ́run wa yóò wá, kò sì ní dákẹ́.+ Iná tó ń jó nǹkan run wà níwájú rẹ̀,+Ìjì tó lágbára sì ń jà ní gbogbo àyíká rẹ̀.+