ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 2:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Á sọ pé: “Èmi fúnra mi ti fi ọba mi jẹ+

      Lórí Síónì,+ òkè mímọ́ mi.”

  • Sáàmù 110:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé:

      “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+

      Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+

       2 Jèhófà yóò na ọ̀pá agbára rẹ jáde láti Síónì, yóò sọ pé:

      “Máa ṣẹ́gun lọ láàárín àwọn ọ̀tá rẹ.”+

  • Mátíù 28:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Jésù sún mọ́ wọn, ó sì sọ fún wọn pé: “Gbogbo àṣẹ ní ọ̀run àti ayé la ti fún mi.+

  • 1 Kọ́ríńtì 15:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Torí ó gbọ́dọ̀ jẹ́ ọba tí á máa ṣàkóso títí Ọlọ́run á fi fi gbogbo àwọn ọ̀tá sí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀.+

  • Éfésù 1:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ó tún fi ohun gbogbo sábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀,+ ó sì fi í ṣe orí lórí ohun gbogbo nínú ìjọ,+

  • Ìfihàn 3:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Màá jẹ́ kí ẹni tó bá ṣẹ́gun+ jókòó pẹ̀lú mi lórí ìtẹ́ mi,+ bí èmi náà ṣe ṣẹ́gun, tí mo sì jókòó+ pẹ̀lú Baba mi lórí ìtẹ́ rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́