-
Dáníẹ́lì 2:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Dáníẹ́lì wá wọlé lọ bá Áríókù, ẹni tí ọba yàn láti pa àwọn amòye Bábílónì run,+ ó sì sọ fún un pé: “Má pa ìkankan nínú àwọn amòye Bábílónì. Mú mi wọlé lọ síwájú ọba, màá sì sọ ìtumọ̀ àlá náà fún ọba.”
-