25 Ó máa sọ̀rọ̀ sí Ẹni Gíga Jù Lọ,+ á sì máa fòòró àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ. Ó máa gbèrò láti yí àwọn àkókò àti òfin pa dà, a sì máa fi wọ́n lé e lọ́wọ́ fún àkókò kan, àwọn àkókò àti ààbọ̀ àkókò.*+
27 “‘A sì fún àwọn èèyàn tó jẹ́ ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ ní ìjọba, àkóso àti títóbi àwọn ìjọba lábẹ́ gbogbo ọ̀run.+ Ìjọba tó máa wà títí láé ni ìjọba wọn,+ gbogbo ìjọba á máa sìn wọ́n, wọ́n á sì máa ṣègbọràn sí wọn.’