-
Dáníẹ́lì 2:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Tí ẹ ò bá sọ àlá náà fún mi, ìyà kan náà ni màá fi jẹ gbogbo yín. Àmọ́ ẹ ti pinnu pé ẹ máa parọ́ fún mi, ẹ sì máa tàn mí jẹ títí dìgbà tí nǹkan fi máa yí pa dà. Torí náà, ẹ rọ́ àlá náà fún mi, màá sì mọ̀ pé ẹ lè sọ ìtumọ̀ rẹ̀.”
-