Dáníẹ́lì 11:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ọba kan tó lágbára máa dìde, ìṣàkóso rẹ̀ máa gbilẹ̀,+ á sì máa ṣe ohun tó wù ú.