Dáníẹ́lì 8:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní ti ìwo tó ṣẹ́, tí mẹ́rin fi jáde dípò rẹ̀,+ ìjọba mẹ́rin máa dìde láti orílẹ̀-èdè rẹ̀, àmọ́ kì í ṣe pẹ̀lú agbára rẹ̀. Dáníẹ́lì 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ tó bá ti dìde, ìjọba rẹ̀ máa fọ́, ó sì máa pín sí ọ̀nà atẹ́gùn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ọ̀run,+ àmọ́ kì í ṣe fún àwọn àtọmọdọ́mọ rẹ̀,* àkóso wọn ò sì ní lágbára bíi tiẹ̀; torí a máa fa ìjọba rẹ̀ tu, ó sì máa di ti àwọn míì yàtọ̀ sí àwọn yìí.
22 Ní ti ìwo tó ṣẹ́, tí mẹ́rin fi jáde dípò rẹ̀,+ ìjọba mẹ́rin máa dìde láti orílẹ̀-èdè rẹ̀, àmọ́ kì í ṣe pẹ̀lú agbára rẹ̀.
4 Àmọ́ tó bá ti dìde, ìjọba rẹ̀ máa fọ́, ó sì máa pín sí ọ̀nà atẹ́gùn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ọ̀run,+ àmọ́ kì í ṣe fún àwọn àtọmọdọ́mọ rẹ̀,* àkóso wọn ò sì ní lágbára bíi tiẹ̀; torí a máa fa ìjọba rẹ̀ tu, ó sì máa di ti àwọn míì yàtọ̀ sí àwọn yìí.