Dáníẹ́lì 10:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mo wá gbọ́ tó ń sọ̀rọ̀; àmọ́ nígbà tí mo gbọ́ tó ń sọ̀rọ̀, mo sùn lọ fọnfọn ní ìdojúbolẹ̀.+ 10 Ọwọ́ kan sì kàn mí,+ ó jí mi pé kí n dìde lórí ọwọ́ mi àti orúnkún mi.
9 Mo wá gbọ́ tó ń sọ̀rọ̀; àmọ́ nígbà tí mo gbọ́ tó ń sọ̀rọ̀, mo sùn lọ fọnfọn ní ìdojúbolẹ̀.+ 10 Ọwọ́ kan sì kàn mí,+ ó jí mi pé kí n dìde lórí ọwọ́ mi àti orúnkún mi.