Dáníẹ́lì 11:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Ní ti ọba méjì yìí, èrò burúkú máa wà lọ́kàn wọn, wọ́n sì máa jókòó sídìí tábìlì kan náà, wọ́n á máa parọ́ fúnra wọn. Àmọ́ kò sóhun tó máa yọrí sí rere, torí kò tíì tó àkókò tí a yàn pé kí òpin dé.+
27 “Ní ti ọba méjì yìí, èrò burúkú máa wà lọ́kàn wọn, wọ́n sì máa jókòó sídìí tábìlì kan náà, wọ́n á máa parọ́ fúnra wọn. Àmọ́ kò sóhun tó máa yọrí sí rere, torí kò tíì tó àkókò tí a yàn pé kí òpin dé.+