Dáníẹ́lì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Lẹ́yìn èyí, mò ń wò, sì wò ó! ẹranko míì tó dà bí àmọ̀tẹ́kùn,+ àmọ́ tó ní ìyẹ́ mẹ́rin bíi ti ẹyẹ ní ẹ̀yìn rẹ̀. Ẹranko náà ní orí mẹ́rin,+ a sì fún un ní àṣẹ láti ṣàkóso.
6 “Lẹ́yìn èyí, mò ń wò, sì wò ó! ẹranko míì tó dà bí àmọ̀tẹ́kùn,+ àmọ́ tó ní ìyẹ́ mẹ́rin bíi ti ẹyẹ ní ẹ̀yìn rẹ̀. Ẹranko náà ní orí mẹ́rin,+ a sì fún un ní àṣẹ láti ṣàkóso.