-
Dáníẹ́lì 8:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ó di ńlá débi pé ó dé ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ ogun ọ̀run lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún, ó sì mú kí àwọn ọmọ ogun kan àti àwọn ìràwọ̀ kan já bọ́ sí ayé, ó sì tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀.
-