Dáníẹ́lì 5:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Òru ọjọ́ yẹn gan-an ni wọ́n pa Bẹliṣásárì, ọba àwọn ará Kálídíà.+ 31 Dáríúsì + ará Mídíà sì gba ìjọba; ọjọ́ orí rẹ̀ jẹ́ nǹkan bí ọdún méjìlélọ́gọ́ta (62).
30 Òru ọjọ́ yẹn gan-an ni wọ́n pa Bẹliṣásárì, ọba àwọn ará Kálídíà.+ 31 Dáríúsì + ará Mídíà sì gba ìjọba; ọjọ́ orí rẹ̀ jẹ́ nǹkan bí ọdún méjìlélọ́gọ́ta (62).