Sáàmù 87:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 87 Ìpìlẹ̀ ìlú rẹ̀ wà lórí àwọn òkè mímọ́.+ 2 Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwọn ẹnubodè Síónì +Ju gbogbo àwọn àgọ́ Jékọ́bù lọ. Sekaráyà 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Èmi yóò pa dà sí Síónì,+ èmi yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ wọ́n á máa pe Jerúsálẹ́mù ní ìlú òtítọ́,*+ wọ́n á sì máa pe òkè Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ní òkè mímọ́.’”+
87 Ìpìlẹ̀ ìlú rẹ̀ wà lórí àwọn òkè mímọ́.+ 2 Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwọn ẹnubodè Síónì +Ju gbogbo àwọn àgọ́ Jékọ́bù lọ.
3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Èmi yóò pa dà sí Síónì,+ èmi yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ wọ́n á máa pe Jerúsálẹ́mù ní ìlú òtítọ́,*+ wọ́n á sì máa pe òkè Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ní òkè mímọ́.’”+