Sáàmù 139:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kódà, òkùnkùn náà kò ní ṣú jù fún ọ,Ṣe ni òru yóò mọ́lẹ̀ bí ọ̀sán;+Ìkan náà ni òkùnkùn àti ìmọ́lẹ̀ lójú rẹ.+ Hébérù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+
12 Kódà, òkùnkùn náà kò ní ṣú jù fún ọ,Ṣe ni òru yóò mọ́lẹ̀ bí ọ̀sán;+Ìkan náà ni òkùnkùn àti ìmọ́lẹ̀ lójú rẹ.+
13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+