-
2 Kọ́ríńtì 1:19, 20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Nítorí Ọmọ Ọlọ́run, Jésù Kristi, tí a wàásù rẹ̀ láàárín yín, ìyẹn nípasẹ̀ èmi àti Sílífánù* pẹ̀lú Tímótì,+ kò di “bẹ́ẹ̀ ni” kó tún wá jẹ́ “bẹ́ẹ̀ kọ́,” àmọ́ “bẹ́ẹ̀ ni” ti di “bẹ́ẹ̀ ni” nínú ọ̀rọ̀ tirẹ̀. 20 Nítorí bó ṣe wù kí àwọn ìlérí Ọlọ́run pọ̀ tó, wọ́n ti di “bẹ́ẹ̀ ni” nípasẹ̀ rẹ̀.+ Torí náà, ipasẹ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ni à ń ṣe “Àmín” sí Ọlọ́run,+ èyí tó ń fi ògo fún un nípasẹ̀ wa.
-