-
Nehemáyà 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Mo sì sọ fún ọba pé: “Tó bá dáa lójú ọba, tí ìránṣẹ́ rẹ bá sì ti rí ojú rere rẹ, kí o rán mi lọ sí Júdà, ní ìlú tí wọ́n sin àwọn baba ńlá mi sí, kí n lè tún un kọ́.”+
-
-
Nehemáyà 2:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Níkẹyìn, mo dé Jerúsálẹ́mù, mo sì lo ọjọ́ mẹ́ta níbẹ̀.
-