-
Lúùkù 3:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ní ọdún kẹẹ̀ẹ́dógún àkóso Tìbéríù Késárì, nígbà tí Pọ́ńtíù Pílátù jẹ́ gómìnà Jùdíà, tí Hẹ́rọ́dù*+ sì jẹ́ alákòóso agbègbè* Gálílì, tí Fílípì arákùnrin rẹ̀ jẹ́ alákòóso agbègbè ilẹ̀ Ítúréà àti Tírákónítì, tí Lísáníà sì jẹ́ alákòóso agbègbè Ábílénè, 2 nígbà ayé Ánásì olórí àlùfáà àti Káyáfà,+ Jòhánù+ ọmọ Sekaráyà gbọ́ ìkéde látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nínú aginjù.+
-