Máàkù 9:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ó sọ fún wọn pé: “Èlíjà máa kọ́kọ́ wá, ó sì máa mú ohun gbogbo pa dà sí bó ṣe yẹ;+ àmọ́ kí wá nìdí tí a fi kọ ọ́ nípa Ọmọ èèyàn pé ó gbọ́dọ̀ jìyà púpọ̀,+ kí wọ́n sì kàn án lábùkù?+
12 Ó sọ fún wọn pé: “Èlíjà máa kọ́kọ́ wá, ó sì máa mú ohun gbogbo pa dà sí bó ṣe yẹ;+ àmọ́ kí wá nìdí tí a fi kọ ọ́ nípa Ọmọ èèyàn pé ó gbọ́dọ̀ jìyà púpọ̀,+ kí wọ́n sì kàn án lábùkù?+