-
Dáníẹ́lì 10:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ó wá ku èmi nìkan, nígbà tí mo sì rí ìran ńlá yìí, agbára kankan ò ṣẹ́ kù nínú mi, ojú mi tó fani mọ́ra tẹ́lẹ̀ yí pa dà, mi ò sì lókun mọ́ rárá.+
-