Àwọn Onídàájọ́ 6:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ìgbà yẹn ni Gídíónì wá mọ̀ pé áńgẹ́lì Jèhófà+ ni. Ojú ẹsẹ̀ ni Gídíónì sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, mo ti rí áńgẹ́lì Jèhófà lójúkojú!”+
22 Ìgbà yẹn ni Gídíónì wá mọ̀ pé áńgẹ́lì Jèhófà+ ni. Ojú ẹsẹ̀ ni Gídíónì sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, mo ti rí áńgẹ́lì Jèhófà lójúkojú!”+