Àìsáyà 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo wá sọ pé: “Mo gbé! Mo ti kú tán,*Torí ọkùnrin tí ètè rẹ̀ kò mọ́ ni mí,Àárín àwọn èèyàn tí ètè wọn ò mọ́ ni mo sì ń gbé;+Torí ojú mi ti rí Ọba, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun fúnra rẹ̀!”
5 Mo wá sọ pé: “Mo gbé! Mo ti kú tán,*Torí ọkùnrin tí ètè rẹ̀ kò mọ́ ni mí,Àárín àwọn èèyàn tí ètè wọn ò mọ́ ni mo sì ń gbé;+Torí ojú mi ti rí Ọba, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun fúnra rẹ̀!”