Dáníẹ́lì 9:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ó sì là mí lóye, ó sọ pé: “Ìwọ Dáníẹ́lì, mo wá láti fún ọ ní ìjìnlẹ̀ òye àti ìmọ̀. 23 Nígbà tí o bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ̀bẹ̀, ọ̀rọ̀ jáde lọ, mo sì wá ròyìn rẹ̀ fún ọ, torí o ṣeyebíye gan-an.*+ Torí náà, ro ọ̀rọ̀ náà, kí ìran náà sì yé ọ. Dáníẹ́lì 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó wá sọ fún mi pé: “Dáníẹ́lì, ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an,*+ fiyè sí ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ sọ fún ọ. Ó yá, dìde níbi tí o wà, torí a ti rán mi sí ọ.” Nígbà tó sọ ọ̀rọ̀ yìí fún mi, mo dìde, mo bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ̀n.
22 Ó sì là mí lóye, ó sọ pé: “Ìwọ Dáníẹ́lì, mo wá láti fún ọ ní ìjìnlẹ̀ òye àti ìmọ̀. 23 Nígbà tí o bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ̀bẹ̀, ọ̀rọ̀ jáde lọ, mo sì wá ròyìn rẹ̀ fún ọ, torí o ṣeyebíye gan-an.*+ Torí náà, ro ọ̀rọ̀ náà, kí ìran náà sì yé ọ.
11 Ó wá sọ fún mi pé: “Dáníẹ́lì, ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an,*+ fiyè sí ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ sọ fún ọ. Ó yá, dìde níbi tí o wà, torí a ti rán mi sí ọ.” Nígbà tó sọ ọ̀rọ̀ yìí fún mi, mo dìde, mo bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ̀n.