Dáníẹ́lì 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ olórí+ ilẹ̀ ọba Páṣíà dí mi lọ́nà fún ọjọ́ mọ́kànlélógún (21). Ṣùgbọ́n Máíkẹ́lì,*+ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ aládé tí ipò wọn ga jù* wá ràn mí lọ́wọ́; mo sì wà níbẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn ọba Páṣíà.
13 Àmọ́ olórí+ ilẹ̀ ọba Páṣíà dí mi lọ́nà fún ọjọ́ mọ́kànlélógún (21). Ṣùgbọ́n Máíkẹ́lì,*+ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ aládé tí ipò wọn ga jù* wá ràn mí lọ́wọ́; mo sì wà níbẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn ọba Páṣíà.