Jẹ́nẹ́sísì 15:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà bá Ábúrámù dá májẹ̀mú+ kan pé: “Ọmọ* rẹ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí,+ láti odò Íjíbítì dé odò ńlá náà, ìyẹn odò Yúfírétì:+ Ìṣe 3:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ẹ̀yin ni ọmọ àwọn wòlíì àti ti májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá àwọn baba ńlá yín dá,+ tí ó sọ fún Ábúráhámù pé: ‘Gbogbo ìdílé tó wà láyé yóò rí ìbùkún nípasẹ̀ ọmọ* rẹ.’+
18 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà bá Ábúrámù dá májẹ̀mú+ kan pé: “Ọmọ* rẹ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí,+ láti odò Íjíbítì dé odò ńlá náà, ìyẹn odò Yúfírétì:+
25 Ẹ̀yin ni ọmọ àwọn wòlíì àti ti májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá àwọn baba ńlá yín dá,+ tí ó sọ fún Ábúráhámù pé: ‘Gbogbo ìdílé tó wà láyé yóò rí ìbùkún nípasẹ̀ ọmọ* rẹ.’+